-
Ẹ́kísódù 19:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Kí o pa ààlà yí òkè náà ká fún àwọn èèyàn náà, kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Ẹ má gun òkè náà, ẹ má sì fara kan ààlà rẹ̀. Ó dájú pé ẹnikẹ́ni tó bá fara kan òkè náà yóò kú.
-