Éfésù 5:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ẹ máa tẹrí ba fún ara yín+ nínú ìbẹ̀rù Kristi. 1 Pétérù 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bákan náà, kí ẹ̀yin ọ̀dọ́kùnrin máa tẹrí ba fún àwọn àgbà ọkùnrin.*+ Àmọ́ kí gbogbo yín gbé ìrẹ̀lẹ̀* wọ̀* nínú àjọṣe yín, torí Ọlọ́run dojú ìjà kọ àwọn agbéraga, àmọ́ ó ń fi inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí hàn sí àwọn onírẹ̀lẹ̀.+
5 Bákan náà, kí ẹ̀yin ọ̀dọ́kùnrin máa tẹrí ba fún àwọn àgbà ọkùnrin.*+ Àmọ́ kí gbogbo yín gbé ìrẹ̀lẹ̀* wọ̀* nínú àjọṣe yín, torí Ọlọ́run dojú ìjà kọ àwọn agbéraga, àmọ́ ó ń fi inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí hàn sí àwọn onírẹ̀lẹ̀.+