Àìsáyà 8:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Màá máa dúró de* Jèhófà,+ ẹni tó ń fi ojú rẹ̀ pa mọ́ fún ilé Jékọ́bù,+ màá sì ní ìrètí nínú rẹ̀.