Nọ́ńbà 14:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ìkankan nínú yín kò ní wọ ilẹ̀ tí mo búra* pé ẹ máa gbé,+ àfi Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè àti Jóṣúà ọmọ Núnì.+ Diutarónómì 31:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Torí mo mọ̀ dáadáa pé ọlọ̀tẹ̀ ni yín,+ ẹ sì lágídí.*+ Tí ẹ bá ń ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà tó báyìí nígbà tí mo ṣì wà láàyè pẹ̀lú yín, tí mo bá wá kú ńkọ́!
30 Ìkankan nínú yín kò ní wọ ilẹ̀ tí mo búra* pé ẹ máa gbé,+ àfi Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè àti Jóṣúà ọmọ Núnì.+
27 Torí mo mọ̀ dáadáa pé ọlọ̀tẹ̀ ni yín,+ ẹ sì lágídí.*+ Tí ẹ bá ń ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà tó báyìí nígbà tí mo ṣì wà láàyè pẹ̀lú yín, tí mo bá wá kú ńkọ́!