Éfésù 6:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Bákan náà, ẹ gba akoto* ìgbàlà+ àti idà ẹ̀mí, ìyẹn, ọ̀rọ̀ Ọlọ́run,+