1 Tẹsalóníkà 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 kí ó lè mú kí ọkàn yín fìdí múlẹ̀, kí ó jẹ́ aláìlẹ́bi nínú jíjẹ́ mímọ́ níwájú Ọlọ́run+ àti Baba wa nígbà tí Jésù Olúwa wa+ bá wà níhìn-ín pẹ̀lú gbogbo àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀.
13 kí ó lè mú kí ọkàn yín fìdí múlẹ̀, kí ó jẹ́ aláìlẹ́bi nínú jíjẹ́ mímọ́ níwájú Ọlọ́run+ àti Baba wa nígbà tí Jésù Olúwa wa+ bá wà níhìn-ín pẹ̀lú gbogbo àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀.