Málákì 3:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Torí èmi ni Jèhófà; èmi kì í yí pa dà.*+ Ẹ̀yin sì ni ọmọ Jékọ́bù; ẹ kò tíì pa run.