-
Jẹ́nẹ́sísì 22:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Níkẹyìn, wọ́n dé ibi tí Ọlọ́run tòótọ́ sọ fún un, Ábúráhámù wá mọ pẹpẹ kan síbẹ̀, ó sì to igi sórí rẹ̀. Ó de Ísákì ọmọ rẹ̀ tọwọ́ tẹsẹ̀, ó sì gbé e sórí igi tó wà lórí pẹpẹ náà.+
-