Jẹ́nẹ́sísì 15:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ábúrámù ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà,+ Ó sì kà á sí òdodo fún un.+ Róòmù 4:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kí ni ìwé mímọ́ sọ? “Ábúráhámù ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà,* ó sì kà á sí òdodo fún un.”+ Gálátíà 3:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Gẹ́gẹ́ bí Ábúráhámù ṣe “ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà,* tí a sì kà á sí òdodo fún un.”+