Sáàmù 146:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ̀mí* rẹ̀ jáde lọ, ó pa dà sínú ilẹ̀;+Ọjọ́ yẹn gan-an ni èrò inú rẹ̀ ṣègbé.+