Róòmù 10:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nítorí ọkàn la fi ń ní ìgbàgbọ́ kí a lè jẹ́ olódodo, àmọ́ ẹnu la fi ń kéde ní gbangba+ kí a lè rí ìgbàlà. Jémíìsì 2:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Bákan náà, ìgbàgbọ́ nìkan láìsí àwọn iṣẹ́ jẹ́ òkú.+
10 Nítorí ọkàn la fi ń ní ìgbàgbọ́ kí a lè jẹ́ olódodo, àmọ́ ẹnu la fi ń kéde ní gbangba+ kí a lè rí ìgbàlà.