-
Sáàmù 39:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Màá fi ìbonu bo ẹnu mi+
Ní gbogbo ìgbà tí ẹni burúkú bá wà níwájú mi.”
-
-
Mátíù 15:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ohun tó ń wọ ẹnu èèyàn kọ́ ló ń sọ èèyàn di aláìmọ́, àmọ́ ohun tó ń ti ẹnu rẹ̀ jáde ló ń sọ ọ́ di aláìmọ́.”+
-
-
Máàkù 7:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Láti inú ni gbogbo nǹkan burúkú yìí ti ń wá, tí wọ́n sì ń sọ èèyàn di aláìmọ́.”
-