Éfésù 4:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Kí ọ̀rọ̀ ìbàjẹ́* má ṣe ti ẹnu yín jáde,+ ọ̀rọ̀ tó ń gbéni ró nìkan ni kí ẹ máa sọ bó bá ṣe yẹ, kí ó lè ṣe àwọn tó ń gbọ́ yín láǹfààní.+
29 Kí ọ̀rọ̀ ìbàjẹ́* má ṣe ti ẹnu yín jáde,+ ọ̀rọ̀ tó ń gbéni ró nìkan ni kí ẹ máa sọ bó bá ṣe yẹ, kí ó lè ṣe àwọn tó ń gbọ́ yín láǹfààní.+