1 Kọ́ríńtì 13:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìfẹ́+ máa ń ní sùúrù*+ àti inú rere.+ Ìfẹ́ kì í jowú,+ kì í fọ́nnu, kì í gbéra ga,+