1 Kọ́ríńtì 2:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ẹni ti ara kì í tẹ́wọ́ gba* àwọn nǹkan ti ẹ̀mí Ọlọ́run, torí wọ́n jẹ́ nǹkan òmùgọ̀ lójú rẹ̀; kò sì lè mọ̀ wọ́n, nítorí ẹ̀mí la fi ń wádìí wọn. Fílípì 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ìparun ni ìgbẹ̀yìn wọn, ikùn wọn ni ọlọ́run wọn, ohun ìtìjú ni wọ́n fi ń ṣògo, àwọn nǹkan ti ayé ni wọ́n sì ń rò.+
14 Ẹni ti ara kì í tẹ́wọ́ gba* àwọn nǹkan ti ẹ̀mí Ọlọ́run, torí wọ́n jẹ́ nǹkan òmùgọ̀ lójú rẹ̀; kò sì lè mọ̀ wọ́n, nítorí ẹ̀mí la fi ń wádìí wọn.
19 Ìparun ni ìgbẹ̀yìn wọn, ikùn wọn ni ọlọ́run wọn, ohun ìtìjú ni wọ́n fi ń ṣògo, àwọn nǹkan ti ayé ni wọ́n sì ń rò.+