1 Tímótì 3:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 kì í ṣe ọ̀mùtí,+ kì í ṣe oníwà ipá,* àmọ́ kó máa fòye báni lò,+ kì í ṣe oníjà,+ kì í ṣe ẹni tó fẹ́ràn owó,+ Títù 3:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 kí wọ́n má sọ̀rọ̀ ẹnì kankan láìdáa, kí wọ́n má ṣe jẹ́ oníjà, kí wọ́n máa fòye báni lò,+ kí wọ́n jẹ́ oníwà tútù sí gbogbo èèyàn.+
3 kì í ṣe ọ̀mùtí,+ kì í ṣe oníwà ipá,* àmọ́ kó máa fòye báni lò,+ kì í ṣe oníjà,+ kì í ṣe ẹni tó fẹ́ràn owó,+
2 kí wọ́n má sọ̀rọ̀ ẹnì kankan láìdáa, kí wọ́n má ṣe jẹ́ oníjà, kí wọ́n máa fòye báni lò,+ kí wọ́n jẹ́ oníwà tútù sí gbogbo èèyàn.+