Mátíù 5:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “Aláyọ̀ ni àwọn tó ń wá àlàáfíà,*+ torí a máa pè wọ́n ní ọmọ Ọlọ́run. 1 Pétérù 3:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Kí ó jáwọ́ nínú ohun búburú,+ kó sì máa ṣe rere;+ kó máa wá àlàáfíà, kó sì máa lépa rẹ̀.+