Éfésù 4:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 ẹ má gba Èṣù láyè.*+ Éfésù 6:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ gbé gbogbo ìhámọ́ra ogun+ láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wọ̀, kí ẹ lè dúró gbọn-in láti dojú kọ àwọn àrékérekè* Èṣù;
11 Ẹ gbé gbogbo ìhámọ́ra ogun+ láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wọ̀, kí ẹ lè dúró gbọn-in láti dojú kọ àwọn àrékérekè* Èṣù;