-
Róòmù 13:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Torí àwọn tó ń ṣàkóso jẹ́ ohun ẹ̀rù, kì í ṣe sí àwọn tó ń ṣe rere, àmọ́ sí àwọn tó ń ṣe búburú.+ Ṣé o kò fẹ́ kí ẹ̀rù aláṣẹ máa bà ọ́? Máa ṣe rere,+ wàá sì gba ìyìn nítorí rẹ̀; 4 torí òjíṣẹ́ Ọlọ́run ló jẹ́ sí ọ fún ire rẹ. Àmọ́ tí o bá ń ṣe ohun búburú, máa bẹ̀rù, nítorí kì í ṣàdédé gbé idà. Òjíṣẹ́ Ọlọ́run ni, ó ń gbẹ̀san láti fi ìrunú hàn sí* ẹni tó ń ṣe ohun búburú.
-