-
Ìṣe 23:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Bí Pọ́ọ̀lù ṣe tẹjú mọ́ Sàhẹ́ndìrìn, ó sọ pé: “Ẹ̀yin èèyàn, ẹ̀yin ará, mo ti hùwà níwájú Ọlọ́run pẹ̀lú ẹ̀rí ọkàn tó mọ́ láìkù síbì kan+ títí di òní yìí.”
-
-
1 Tímótì 3:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 kí wọ́n ní ẹ̀rí ọkàn tó mọ́+ bí wọ́n ti ń rọ̀ mọ́ àṣírí mímọ́ ti ìgbàgbọ́.
-