-
1 Kọ́ríńtì 15:50Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
50 Àmọ́ mo sọ fún yín, ẹ̀yin ará, pé ara àti ẹ̀jẹ̀ kò lè jogún Ìjọba Ọlọ́run, bẹ́ẹ̀ ni ìdíbàjẹ́ kì í jogún àìdíbàjẹ́.