Mátíù 13:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín pé, ó wu ọ̀pọ̀ àwọn wòlíì àti àwọn olódodo pé kí wọ́n rí àwọn ohun tí ẹ̀ ń rí, àmọ́ wọn ò rí i,+ ó wù wọ́n kí wọ́n gbọ́ àwọn ohun tí ẹ̀ ń gbọ́, àmọ́ wọn ò gbọ́ ọ.
17 Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín pé, ó wu ọ̀pọ̀ àwọn wòlíì àti àwọn olódodo pé kí wọ́n rí àwọn ohun tí ẹ̀ ń rí, àmọ́ wọn ò rí i,+ ó wù wọ́n kí wọ́n gbọ́ àwọn ohun tí ẹ̀ ń gbọ́, àmọ́ wọn ò gbọ́ ọ.