1 Pétérù 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 kí ìgbàgbọ́ yín tí a dán wò+ ní ti bó ṣe jẹ́ ojúlówó tó, èyí tó níye lórí gidigidi ju wúrà tó máa ń ṣègbé láìka pé a fi iná dá an wò* sí, lè jẹ́ orísun ìyìn àti ògo àti ọlá nígbà ìfihàn Jésù Kristi.+
7 kí ìgbàgbọ́ yín tí a dán wò+ ní ti bó ṣe jẹ́ ojúlówó tó, èyí tó níye lórí gidigidi ju wúrà tó máa ń ṣègbé láìka pé a fi iná dá an wò* sí, lè jẹ́ orísun ìyìn àti ògo àti ọlá nígbà ìfihàn Jésù Kristi.+