2 Kọ́ríńtì 1:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Kì í ṣe pé a jẹ́ ọ̀gá lórí ìgbàgbọ́ yín,+ àmọ́ a jọ ń ṣiṣẹ́ kí ẹ lè máa láyọ̀, torí ìgbàgbọ́ yín ló mú kí ẹ dúró.
24 Kì í ṣe pé a jẹ́ ọ̀gá lórí ìgbàgbọ́ yín,+ àmọ́ a jọ ń ṣiṣẹ́ kí ẹ lè máa láyọ̀, torí ìgbàgbọ́ yín ló mú kí ẹ dúró.