Jòhánù 15:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Nígbà tí olùrànlọ́wọ́ tí màá rán sí yín látọ̀dọ̀ Baba bá dé, ẹ̀mí òtítọ́,+ tó wá látọ̀dọ̀ Baba, ó máa jẹ́rìí nípa mi;+ Ìṣe 2:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 gbogbo wọn wá kún fún ẹ̀mí mímọ́,+ wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í sọ oríṣiríṣi èdè,* bí ẹ̀mí ṣe mú kí wọ́n máa sọ̀rọ̀.+
26 Nígbà tí olùrànlọ́wọ́ tí màá rán sí yín látọ̀dọ̀ Baba bá dé, ẹ̀mí òtítọ́,+ tó wá látọ̀dọ̀ Baba, ó máa jẹ́rìí nípa mi;+
4 gbogbo wọn wá kún fún ẹ̀mí mímọ́,+ wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í sọ oríṣiríṣi èdè,* bí ẹ̀mí ṣe mú kí wọ́n máa sọ̀rọ̀.+