ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 11:44
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 44 Torí èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín,+ ẹ gbọ́dọ̀ ya ara yín sí mímọ́, kí ẹ sì di mímọ́,+ torí mo jẹ́ mímọ́.+ Torí náà, ẹ ò gbọ́dọ̀ fi ẹ̀dá èyíkéyìí tó ń gbá yìn-ìn lórí ilẹ̀ sọ ara yín* di aláìmọ́.

  • Léfítíkù 19:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Sọ fún gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Kí ẹ jẹ́ mímọ́, torí èmi Jèhófà Ọlọ́run yín jẹ́ mímọ́.+

  • Léfítíkù 20:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 “‘Kí ẹ ya ara yín sí mímọ́, kí ẹ sì di mímọ́,+ torí èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.

  • Léfítíkù 20:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Kí ẹ jẹ́ mímọ́ fún mi, torí èmi Jèhófà jẹ́ mímọ́,+ mo sì ń yà yín sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn èèyàn yòókù kí ẹ lè di tèmi.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́