Jòhánù 14:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jésù sọ fún un pé: “Èmi ni ọ̀nà+ àti òtítọ́ + àti ìyè.+ Kò sí ẹni tó ń wá sọ́dọ̀ Baba àfi nípasẹ̀ mi.+
6 Jésù sọ fún un pé: “Èmi ni ọ̀nà+ àti òtítọ́ + àti ìyè.+ Kò sí ẹni tó ń wá sọ́dọ̀ Baba àfi nípasẹ̀ mi.+