1 Tímótì 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní tòótọ́, ìdí tí mo fi ń sọ ìtọ́ni* yìí jẹ́ nítorí ìfẹ́+ látinú ọkàn tó mọ́, látinú ẹ̀rí ọkàn rere àti látinú ìgbàgbọ́+ tí kò ní àgàbàgebè.
5 Ní tòótọ́, ìdí tí mo fi ń sọ ìtọ́ni* yìí jẹ́ nítorí ìfẹ́+ látinú ọkàn tó mọ́, látinú ẹ̀rí ọkàn rere àti látinú ìgbàgbọ́+ tí kò ní àgàbàgebè.