Gálátíà 5:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àmọ́ mo sọ pé, Ẹ máa rìn nípa ẹ̀mí,+ ẹ kò sì ní ṣe ìfẹ́ ti ara rárá.+ Jémíìsì 1:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Torí náà, ẹ mú gbogbo èérí àti gbogbo ohun tó jẹ mọ́ ìwà burúkú* kúrò,+ kí ìwà tútù yín sì mú kí ọ̀rọ̀ tó lè gbà yín là* fìdí múlẹ̀ nínú yín.
21 Torí náà, ẹ mú gbogbo èérí àti gbogbo ohun tó jẹ mọ́ ìwà burúkú* kúrò,+ kí ìwà tútù yín sì mú kí ọ̀rọ̀ tó lè gbà yín là* fìdí múlẹ̀ nínú yín.