Róòmù 13:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kí gbogbo èèyàn* máa tẹrí ba fún àwọn aláṣẹ onípò gíga,+ nítorí kò sí àṣẹ kankan àfi èyí tó wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run;+ àwọn aláṣẹ tó wà ni a gbé sí àwọn ipò wọn tó ní ààlà látọ̀dọ̀ Ọlọ́run.+ Éfésù 6:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ̀yin ẹrú, ẹ máa gbọ́ràn sí àwọn ọ̀gá yín* lẹ́nu,+ pẹ̀lú ìbẹ̀rù àti ìwárìrì nínú òótọ́ ọkàn, gẹ́gẹ́ bíi sí Kristi, Títù 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Máa rán wọn létí pé kí wọ́n máa tẹrí ba fún ìjọba àti àwọn aláṣẹ, kí wọ́n máa ṣègbọràn sí wọn,+ kí wọ́n sì múra tán láti máa ṣe iṣẹ́ rere gbogbo,
13 Kí gbogbo èèyàn* máa tẹrí ba fún àwọn aláṣẹ onípò gíga,+ nítorí kò sí àṣẹ kankan àfi èyí tó wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run;+ àwọn aláṣẹ tó wà ni a gbé sí àwọn ipò wọn tó ní ààlà látọ̀dọ̀ Ọlọ́run.+
5 Ẹ̀yin ẹrú, ẹ máa gbọ́ràn sí àwọn ọ̀gá yín* lẹ́nu,+ pẹ̀lú ìbẹ̀rù àti ìwárìrì nínú òótọ́ ọkàn, gẹ́gẹ́ bíi sí Kristi,
3 Máa rán wọn létí pé kí wọ́n máa tẹrí ba fún ìjọba àti àwọn aláṣẹ, kí wọ́n máa ṣègbọràn sí wọn,+ kí wọ́n sì múra tán láti máa ṣe iṣẹ́ rere gbogbo,