Léfítíkù 19:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 “‘Kí o dìde níwájú orí ewú,+ kí o máa bọlá fún àgbàlagbà,+ kí o sì máa bẹ̀rù Ọlọ́run+ rẹ. Èmi ni Jèhófà. Róòmù 12:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nínú ìfẹ́ ará, ẹ ní ìfẹ́ oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ fún ara yín. Nínú bíbu ọlá fún ara yín, ẹ mú ipò iwájú.*+ Róòmù 13:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹ fún gbogbo èèyàn ní ohun tí ó tọ́ sí wọn: ẹni tó béèrè owó orí, ẹ fún un ní owó orí;+ ẹni tó béèrè ìṣákọ́lẹ̀,* ẹ fún un ní ìṣákọ́lẹ̀; ẹni tí ìbẹ̀rù yẹ, ẹ bẹ̀rù rẹ̀ bó ṣe yẹ;+ ẹni tí ọlá yẹ, ẹ bọlá fún un bó ṣe yẹ.+
32 “‘Kí o dìde níwájú orí ewú,+ kí o máa bọlá fún àgbàlagbà,+ kí o sì máa bẹ̀rù Ọlọ́run+ rẹ. Èmi ni Jèhófà.
7 Ẹ fún gbogbo èèyàn ní ohun tí ó tọ́ sí wọn: ẹni tó béèrè owó orí, ẹ fún un ní owó orí;+ ẹni tó béèrè ìṣákọ́lẹ̀,* ẹ fún un ní ìṣákọ́lẹ̀; ẹni tí ìbẹ̀rù yẹ, ẹ bẹ̀rù rẹ̀ bó ṣe yẹ;+ ẹni tí ọlá yẹ, ẹ bọlá fún un bó ṣe yẹ.+