1 Pétérù 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹ jẹ́ oníwà rere láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ kó lè jẹ́ pé tí wọ́n bá fẹ̀sùn ìwà ibi kàn yín, wọ́n á lè fojú ara wọn rí àwọn iṣẹ́ àtàtà yín,+ kí wọ́n sì torí ẹ̀ yin Ọlọ́run lógo lọ́jọ́ àbẹ̀wò rẹ̀.
12 Ẹ jẹ́ oníwà rere láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ kó lè jẹ́ pé tí wọ́n bá fẹ̀sùn ìwà ibi kàn yín, wọ́n á lè fojú ara wọn rí àwọn iṣẹ́ àtàtà yín,+ kí wọ́n sì torí ẹ̀ yin Ọlọ́run lógo lọ́jọ́ àbẹ̀wò rẹ̀.