-
Róòmù 15:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Àmọ́ ṣá, mo ti kọ̀wé sí yín lọ́nà tó túbọ̀ ṣe ṣàkó lórí àwọn kókó kan, kí n lè tún rán yín létí, nítorí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tí Ọlọ́run fún mi,
-