1 Kọ́ríńtì 6:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 nítorí a ti rà yín ní iye kan.+ Nítorí náà, ẹ máa yin Ọlọ́run lógo+ nínú ara yín.+