Júùdù 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ṣùgbọ́n àwọn èèyàn yìí ń sọ ohun tí kò dáa nípa gbogbo ohun tí wọn kò mọ̀.+ Gbogbo ohun tí wọ́n mọ̀ bíi ti ẹranko tí kì í ronú,+ ni wọ́n fi ń sọ ara wọn di ẹlẹ́gbin.
10 Ṣùgbọ́n àwọn èèyàn yìí ń sọ ohun tí kò dáa nípa gbogbo ohun tí wọn kò mọ̀.+ Gbogbo ohun tí wọ́n mọ̀ bíi ti ẹranko tí kì í ronú,+ ni wọ́n fi ń sọ ara wọn di ẹlẹ́gbin.