ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Júùdù 12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Àwọn yìí máa ń wà níbi àsè tí ẹ fìfẹ́ pe ara yín sí,+ àmọ́ wọ́n dà bí àpáta tó fara pa mọ́ lábẹ́ omi. Olùṣọ́ àgùntàn tí kò bẹ̀rù Ọlọ́run ni wọ́n, ara wọn nìkan ni wọ́n ń bọ́.+ Wọ́n dà bí ìkùukùu* tí kò lómi tí atẹ́gùn ń gbá síbí sọ́hùn-ún.+ Wọ́n dà bí igi tí kò léso nígbà ìwọ́wé, tó ti kú pátápátá,* tí a ti hú tegbòtegbò;

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́