1 Pétérù 2:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ẹ wà lómìnira,+ kí ẹ má sì fi òmìnira yín bojú* láti máa hùwà burúkú,+ àmọ́ kí ẹ lò ó bí ẹrú Ọlọ́run.+
16 Ẹ wà lómìnira,+ kí ẹ má sì fi òmìnira yín bojú* láti máa hùwà burúkú,+ àmọ́ kí ẹ lò ó bí ẹrú Ọlọ́run.+