Lúùkù 12:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Nígbà náà, ẹrú yẹn tó lóye ohun tí ọ̀gá rẹ̀ fẹ́ àmọ́ tí kò múra sílẹ̀, tí kò sì ṣe ohun tó ní kó ṣe* la máa nà ní ẹgba tó pọ̀.+ Jòhánù 15:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ká ní mi ò wá bá wọn sọ̀rọ̀ ni, wọn ò ní ní ẹ̀ṣẹ̀ kankan.+ Àmọ́ ní báyìí, wọn ò ní àwíjàre kankan fún ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+
47 Nígbà náà, ẹrú yẹn tó lóye ohun tí ọ̀gá rẹ̀ fẹ́ àmọ́ tí kò múra sílẹ̀, tí kò sì ṣe ohun tó ní kó ṣe* la máa nà ní ẹgba tó pọ̀.+
22 Ká ní mi ò wá bá wọn sọ̀rọ̀ ni, wọn ò ní ní ẹ̀ṣẹ̀ kankan.+ Àmọ́ ní báyìí, wọn ò ní àwíjàre kankan fún ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+