25 Gbogbo àwọn tó ń kópa nínú ìdíje* ló máa ń kíyè sára nínú ohun gbogbo. Lóòótọ́, wọ́n ń ṣe é kí wọ́n lè gba adé tó lè bà jẹ́,+ àmọ́ àwa ń ṣe bẹ́ẹ̀ ká lè gba èyí tí kò lè bà jẹ́.+
24 Torí pé kò yẹ kí ẹrú Olúwa máa jà, àmọ́ ó yẹ kó máa hùwà jẹ́jẹ́* sí gbogbo èèyàn,+ kí ó kúnjú ìwọ̀n láti kọ́ni, kó máa kó ara rẹ̀ níjàánu tí wọ́n bá ṣe ohun tí kò dáa sí i,+