1 Tẹsalóníkà 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àmọ́, ní ti ìfẹ́ ará,+ ẹ kò nílò ká kọ̀wé sí yín, nítorí Ọlọ́run ti kọ́ yín láti máa nífẹ̀ẹ́ ara yín.+
9 Àmọ́, ní ti ìfẹ́ ará,+ ẹ kò nílò ká kọ̀wé sí yín, nítorí Ọlọ́run ti kọ́ yín láti máa nífẹ̀ẹ́ ara yín.+