Jòhánù 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 nípasẹ̀ rẹ̀ ni ìyè, ìyè náà sì ni ìmọ́lẹ̀ àwọn èèyàn.+ Jòhánù 6:68 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 68 Símónì Pétérù dá a lóhùn pé: “Olúwa, ọ̀dọ̀ ta la máa lọ?+ Ìwọ lo ní àwọn ọ̀rọ̀ ìyè àìnípẹ̀kun.+