23 Ẹnikẹ́ni tó bá sẹ́ Ọmọ kò ní Baba.+ Ẹnikẹ́ni tó bá sọ pé òun mọ Ọmọ+ ní Baba pẹ̀lú.+ 24 Ní tiyín, àwọn nǹkan tí ẹ ti gbọ́ láti ìbẹ̀rẹ̀ kò gbọ́dọ̀ kúrò nínú yín.+ Tí àwọn nǹkan tí ẹ ti gbọ́ láti ìbẹ̀rẹ̀ kò bá kúrò nínú yín, ẹ̀yin àti Ọmọ máa wà ní ìṣọ̀kan, ẹ sì máa wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Baba.