Jòhánù 16:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Mo ti sọ àwọn nǹkan yìí fún yín kí ẹ lè ní àlàáfíà nípasẹ̀ mi.+ Ẹ máa ní ìpọ́njú nínú ayé, àmọ́ ẹ mọ́kàn le! Mo ti ṣẹ́gun ayé.”+ 1 Jòhánù 5:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 A mọ̀ pé gbogbo ẹni tí a ti bí látọ̀dọ̀ Ọlọ́run kì í sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà, àmọ́ ẹni tí a bí látọ̀dọ̀ Ọlọ́run* ń ṣọ́ ọ, ẹni burúkú náà ò sì lè rí i mú.*+
33 Mo ti sọ àwọn nǹkan yìí fún yín kí ẹ lè ní àlàáfíà nípasẹ̀ mi.+ Ẹ máa ní ìpọ́njú nínú ayé, àmọ́ ẹ mọ́kàn le! Mo ti ṣẹ́gun ayé.”+
18 A mọ̀ pé gbogbo ẹni tí a ti bí látọ̀dọ̀ Ọlọ́run kì í sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà, àmọ́ ẹni tí a bí látọ̀dọ̀ Ọlọ́run* ń ṣọ́ ọ, ẹni burúkú náà ò sì lè rí i mú.*+