Éfésù 4:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ẹ mú gbogbo inú burúkú,+ ìbínú, ìrunú, ariwo àti ọ̀rọ̀ èébú kúrò lọ́dọ̀ yín,+ títí kan gbogbo ohun tó lè ṣeni léṣe.+ Kólósè 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ ní báyìí, ẹ gbọ́dọ̀ mú gbogbo wọn kúrò lọ́dọ̀ yín: ìrunú, ìbínú, ìwà burúkú+ àti ọ̀rọ̀ èébú,+ kí ẹ sì mú ọ̀rọ̀ rírùn+ kúrò lẹ́nu yín.
31 Ẹ mú gbogbo inú burúkú,+ ìbínú, ìrunú, ariwo àti ọ̀rọ̀ èébú kúrò lọ́dọ̀ yín,+ títí kan gbogbo ohun tó lè ṣeni léṣe.+
8 Àmọ́ ní báyìí, ẹ gbọ́dọ̀ mú gbogbo wọn kúrò lọ́dọ̀ yín: ìrunú, ìbínú, ìwà burúkú+ àti ọ̀rọ̀ èébú,+ kí ẹ sì mú ọ̀rọ̀ rírùn+ kúrò lẹ́nu yín.