Mátíù 5:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Àmọ́ mò ń sọ fún yín pé ẹnikẹ́ni tó bá tẹjú mọ́ obìnrin+ kan lọ́nà tí á fi wù ú láti bá a ṣe ìṣekúṣe, ó ti bá a ṣe àgbèrè nínú ọkàn rẹ̀.+ Róòmù 13:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àmọ́, ẹ gbé Olúwa Jésù Kristi wọ̀,+ ẹ má sì máa gbèrò àwọn ìfẹ́ ti ara.+
28 Àmọ́ mò ń sọ fún yín pé ẹnikẹ́ni tó bá tẹjú mọ́ obìnrin+ kan lọ́nà tí á fi wù ú láti bá a ṣe ìṣekúṣe, ó ti bá a ṣe àgbèrè nínú ọkàn rẹ̀.+