Jòhánù 17:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Èyí túmọ̀ sí ìyè àìnípẹ̀kun,+ pé kí wọ́n wá mọ ìwọ Ọlọ́run tòótọ́ kan ṣoṣo*+ àti Jésù Kristi,+ ẹni tí o rán. 1 Jòhánù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 (òótọ́ ni, a fi ìyè náà hàn kedere, a ti rí ìyè àìnípẹ̀kun+ tó wà pẹ̀lú Baba, tí a fi hàn kedere fún wa, à ń jẹ́rìí fún yín nípa rẹ̀,+ a sì ń ròyìn rẹ̀ fún yín),
3 Èyí túmọ̀ sí ìyè àìnípẹ̀kun,+ pé kí wọ́n wá mọ ìwọ Ọlọ́run tòótọ́ kan ṣoṣo*+ àti Jésù Kristi,+ ẹni tí o rán.
2 (òótọ́ ni, a fi ìyè náà hàn kedere, a ti rí ìyè àìnípẹ̀kun+ tó wà pẹ̀lú Baba, tí a fi hàn kedere fún wa, à ń jẹ́rìí fún yín nípa rẹ̀,+ a sì ń ròyìn rẹ̀ fún yín),