Jòhánù 15:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Tí ẹ bá jẹ́ apá kan ayé, ayé máa nífẹ̀ẹ́ ohun tó jẹ́ tirẹ̀. Torí pé ẹ kì í ṣe apá kan ayé,+ àmọ́ mo ti yàn yín látinú ayé, torí èyí ni ayé ṣe kórìíra yín.+
19 Tí ẹ bá jẹ́ apá kan ayé, ayé máa nífẹ̀ẹ́ ohun tó jẹ́ tirẹ̀. Torí pé ẹ kì í ṣe apá kan ayé,+ àmọ́ mo ti yàn yín látinú ayé, torí èyí ni ayé ṣe kórìíra yín.+