-
2 Jòhánù 5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Torí náà, mò ń rọ̀ ẹ́, ìwọ obìnrin, (àṣẹ tí a ní láti ìbẹ̀rẹ̀ ni mò ń kọ̀wé rẹ̀ sí ọ, kì í ṣe àṣẹ tuntun), pé ó yẹ ká nífẹ̀ẹ́ ara wa.+
-