16 “Torí Ọlọ́run nífẹ̀ẹ́ ayé gan-an débi pé ó fi Ọmọ bíbí rẹ̀ kan ṣoṣo fúnni,+ kí gbogbo ẹni tó bá ń ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀ má bàa pa run, ṣùgbọ́n kó lè ní ìyè àìnípẹ̀kun.+
13Torí pé Jésù ti mọ̀ ṣáájú àjọyọ̀ Ìrékọjá pé wákàtí òun ti tó+ láti kúrò ní ayé yìí lọ sọ́dọ̀ Baba,+ ó nífẹ̀ẹ́ àwọn tirẹ̀ tó wà ní ayé, ó sì nífẹ̀ẹ́ wọn dé òpin.+