1 Jòhánù 2:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ta ni òpùrọ́ tí kì í bá ṣe ẹni tó sọ pé Jésù kọ́ ni Kristi?+ Ẹni yìí ni aṣòdì sí Kristi,+ ẹni tó sẹ́ Baba àti Ọmọ.
22 Ta ni òpùrọ́ tí kì í bá ṣe ẹni tó sọ pé Jésù kọ́ ni Kristi?+ Ẹni yìí ni aṣòdì sí Kristi,+ ẹni tó sẹ́ Baba àti Ọmọ.